Home / Test2page 100

Test2

Ounje Emi Fun T’ooro Yii – 29.07.2016

HUN !!! ‪ Otito‬ wa da bi ‪ ‎Akisa Elegbin‬ ni niwaju ‪ Oluwa‬ … WOO ORE WA !! Bawo lo se roo pe o mo (mi) to… Nje iwo ri ara re gege bi ‪‎Ododo‬ loju gbogbo aye ? ...

Read More »

Ogbon O Di Igi A Fi Okun(Rope) …

Ojulu, ti opo-eniyan bama wi won a ni ogbon o di igi a fi okun(rope) won a tun ni kosi abuja(short-cut) lorun ope, sugbon ogbon di igi fun eni ti eledua ba gbon, be sini abuja ‘be lorun ope ti ...

Read More »

Olojo Ibi Ti Oni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa Omolola Adex ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Maami Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re ...

Read More »

Ire ni mo ko

Ire ni mo ji ri Ire tororo d’ori awa o Ire toorun ogberi o mo o Aase   IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole

Read More »

Odu ifa IROSUN OPINNI/ IROSUN ORO

| | | | | | | | | | |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, gegebi oni se je ojo isegun olorun alagbara yio muwa bori Ogun ota ase. Odu ifa IROSUN OPINNI/ ...

Read More »

Iwure owuro 26.07.2016

*Aje ko ni di ota a mi. *Edumare dakun fidi aje sole nile mi. *Imo ota, imo elenini ko ni se lori mi. *Emi ko ni di eni arisa ati arisunkun. *Edumare fi aso iyi wo mi(Ase). Aare Olasunkanmi Alani ...

Read More »

Ore yeye Osun!

May we all be blessed today and beyond. Ore yeye Osun! Take it to the river. Ore yeye Osun! – – –  

Read More »

Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro, egbo bose wi

Olotu: ekasan ooo eyin ara ile,asiku asiko yin, eledua yowa pelu gbogbo wa o,ase. Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro egbo bose wic….Gbogbo eyin ebi mofe ki e fi ise yin bura fun mi pe ti moba so e ...

Read More »

Alaso funfun

Cc- Yèyé Èkìtì‎

Read More »

Odu ifa IROSUN ATAPO – Faniyi David Osagbami

 |    |  |    | | |  | | | | |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, bi a se njade lo laaro yi pelu ayo ati alaafia a koni pada sile pelu ...

Read More »