Oba’binrin Asa Solaade Iyaasa: Ohun IFA ati Iwure
ÒÒṢÀ ÒKÈ, ÌBÀ IFA ni ti a ba ji a ki OLU OLU moji mo ki o loni IFA ni to a ba ji a ki Osin, osin moji mo ki o loni ELA ni kan ni somo bibi inu ...
Read More »
ÒÒṢÀ ÒKÈ, ÌBÀ IFA ni ti a ba ji a ki OLU OLU moji mo ki o loni IFA ni to a ba ji a ki Osin, osin moji mo ki o loni ELA ni kan ni somo bibi inu ...
Read More »Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo ...
Read More »Die ni yii ninu ibudo ere fiimu tuntun Kunle Afolayan, The CEO, ni ilu Nairobi to wa ni Kenya.
Read More »Titi Masha ni yii, okan ninu awon orekelewa obirin ti K1 de Ultimate fi n segbaladun niyewu. Titi rewa pupo lobirin, oju re ri rekete bi ojo, ibadi aran ti n danilorun nigba gbogbo. [Olayemi, ara n fu mi si ...
Read More »Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman Dambazzau lo soju ...
Read More »Ojo gbobo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon igara olosa kan segi laaro ana ni agbegbe Olowotedo Mowe to wa ni masose Eko si Ibadan. Ikanra ni awon eniyan agbegbe naa fi na awon ole taa ...
Read More »Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose tun gbe ara mii yo pelu bo se gba obe alapata mu niso alapata eran to si bere si ni ge eran fun awon kositoma.
Read More »Dayo Amusa rode ariya lonii ojo Satide. Omobirin naa si se afihan foto re ko to jade kuro nile. Ka ma paro, Alhaja yii fine gan-an.
Read More »