Awon aye tun pade Fayose nile alapata
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose tun gbe ara mii yo pelu bo se gba obe alapata mu niso alapata eran to si bere si ni ge eran fun awon kositoma.
Read More »
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose tun gbe ara mii yo pelu bo se gba obe alapata mu niso alapata eran to si bere si ni ge eran fun awon kositoma.
Read More »Dayo Amusa rode ariya lonii ojo Satide. Omobirin naa si se afihan foto re ko to jade kuro nile. Ka ma paro, Alhaja yii fine gan-an.
Read More »Odun Thaipuisam je orisii odun kan ti awon elesin Hindu ti won gbe ni Guusu apa orileede ile India ma n se. Ninu odun yii ni awon eniyan ti maa fi irin sonso orisiirisii gun ara won ni gbogbo ara. ...
Read More »Mo ri okunrin aro kan ti ko lapa kan lori afara ti awon elese n gba soda niluu Eko. Okunrin naa n fi igbale gba gbogbo ori afara laise wi pe enikeni gbese naa fun. Isesi okunrin naa wu mi ...
Read More »Eyi ni die lara awon foto to jade nibi eye ikeyin ti won se fun Mama HID Awolowo eni ti won pada sin lojo karunlelogun osu kokanla odun yii, 25/11/15. E tesiwaju lati wo awon foto to ku.
Read More »Leyin gbogbo rukerudo oselu to ti n sele nipinle Kogi, eleyii to bere leyin iku Abubakar Audu, awon egbe APC ti yan Yahaya Bello gege bi eni ti yoo ropo Audu to ku. Ogbeni James Faleke naa si ni won ...
Read More »Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i ...
Read More »*Faleke n binu, ara ilu n sofo *Iwe ofin ruju mo awon amofin loju *Won tun ni kan fomo Audu je gomina apapandodo Leyin iku Abubakar Audu, oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Kogi, eni to jade ...
Read More »Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije ...
Read More »