Arákùnrin kan ni ó na ìyàwó rè, tí ó sì ba àwò ara ré je.
Arákùnrin kan ni a gbó wípé ó na ìyàwó rè tí ó sì dá àpá si lára, ládúrú bí won ti se n kó wa ní èkó lórí bí a se le gbé lókoláya tó. Bí ó tilè jé wípé ...
Read More »
Arákùnrin kan ni a gbó wípé ó na ìyàwó rè tí ó sì dá àpá si lára, ládúrú bí won ti se n kó wa ní èkó lórí bí a se le gbé lókoláya tó. Bí ó tilè jé wípé ...
Read More »Ogúnjó osù kejo (20/8) odoodún ni odún ìsèsi màa ń wáyé káàkiri àgbáyé. Ìlú kòòkan ni ó sì máa ń se odún náà sùgbón àwon ìpínlè Kan wà tí won máa ń se é papò bí ìpínlè Osun. Àjòdún odún ...
Read More »Ao bo isese o, ao bo isese olowo o, isese o lao bo o, kawa to borisa o, BABA mi isese, IYA mi isese, lao bo o, kawa to borisa o, ORI mi isese, IKIN mi isese, lao bo o, ...
Read More »Ní òwúrò ànà tí se ojó Àìkú ní ariwo ta ní ìlú Ibadan ní ìpínlè Oyo nígbà tí ijoba ìpínlè náà pàse kí won wó ilé-isé ìròyìn ti Yinka Ayefele tí a mò sí Fresh Fm tí ó wà ní ...
Read More »Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Aregbesola ti kéde oludé fún gbogbo òsìsé ìjoba fún odún ìsèsí tí yóò wáyé ní òla ogúnjó osù kejo odún 2018.Asèyí se àmódún, ìsèsi á gbè wá oooo. Ìsèsi á gbè wá o.
Read More »Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá. Ní òpópónà Uselu ní ìlú Benin ti ìpínlè Edo ni àgbàrá ti gbalè gbalé léyìn òjò ñlá tí ó rò . òpòlopò okò ti omi gbé lo, òpó ...
Read More »Gégé bí a ti mo wípé òkan gbógì ní ilé-èkó gíga Òbafemi Awolowo University (OAU) jé ní orílè èdè Nìjíríà yí. Sà déédéé ni a gbó wípé arábìnrin kan tí ó jé akékòó ilé-èkó yí ya wèrè látàrí ìwé kíkà ...
Read More »Òsun Osogbo tún ti dé lónìí tí se ojó ketaàdínlógún osù kejo odún, 2018, tí gbogbo àgbàyé fi n se odún fún Òsun éléyinjú àánú, igbómolè obìnrin Òsàyòmolè Nílé ìyà olúgbón won kò gbodò mawo Ìran arèsè kò gbodò morò ...
Read More »Gbajúgbajà òsèré, Joke Silver so wípé nse ni olóògbé E.A Silver àti Dr.Abimbola Silver gba òun tó ni sùgbón nse ni kìí se wípé òun kò mò télè . Joke Silver so wípé nígbà tí ó yá ni oko òun ...
Read More »oni ti ilè-ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi tí òun àti olorì télè èyí tí a mò sí olorì Wuraola tí pínyà ní osú ògún tí a mò sí odù kejo odún 2017, nse ni ó dàbí baba ti rí olólùfé ...
Read More »