Ògún lákáayé .
Ọ̀wọ́nyán rosùn porogodo lóso, Agogo ńlá ni wọ́n fi ń fọ́ri fálágbára mu, Àtàtà ńlá ni wọ́n fi ń fọ yíìrí mọrọ̀, Adífáfún Ògún tíń gbógun lọ sí Ìgbòmẹkùn-eséji, ẹbọ lawo níkóse, Ògún ló sẹbọ sètùtù lówá kóre dé ìtùtúrú ...
Read More »