Alágemo tó se jéjé ikú pa á.
Kí á dijú ká se bí eni tí ó kú kí á wo eni tí yó se ìdárò eni Ká fi esè ko gbàù kí á wo eni tí yó seni pèlé Ayé laó ti mo eni tí ó ń ...
Read More »
Kí á dijú ká se bí eni tí ó kú kí á wo eni tí yó se ìdárò eni Ká fi esè ko gbàù kí á wo eni tí yó seni pèlé Ayé laó ti mo eni tí ó ń ...
Read More »Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà. Ìyáawa Grace Atinuke, tí won bí ní ojó kerìndínlógún osù beelu ní odún 1931, tí a mò sí eni tí ó kókó gba àmì ...
Read More »Nìjíríà àfi kí olórun gbà wá lówó gbogbo hílàhílo tí ó ń selè yí, irú kí leléyìí báyìí . Eléyìí ló selè ní Oghara. arábìnrin kan ni ó ún gun òkadà lo tí ó sì gbé epo beetíròlù séyìn nígbà ...
Read More »Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU). Ìsèlè burúkú gbáà ní Óní selè ní ojó kewàá osù keje odún 1999 ní ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university nígbà tí èmi oní inú ire sì gba ibè lo. Afrika ...
Read More ». AJE NIMO FẸẸ! Ohun aje f’oju miri ẹnu o le sọ; Oju miri to lori ọrọ aje; Owo(business) f’ẹgbin rẹmi lara; Ninu ẹgbin lọla fiṣe ile; Ọrọ kobakungbe inu iṣẹ-aje ni ngbe. Aje ogugu ni sọ; Onisọ iboji o; ...
Read More »Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun. Arákùnrin kan ni ó so àwon táyà okò tí ó ti bàjé yí di tábìlì aláfé, okùnrin yí tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà. Kí ...
Read More »John, Peter àti Jamie Obidiegwu, ìbeta se ayeye ojó ìbí won ní àrà òtò. Ayeye ojó ìbí míràn ni ó jé fún àwon ìbeta tí ó jé okùnrin yí, ohun ayò ni ayeye yí sì jé fún won tí won ...
Read More »Arákùnrin tí ó ń se isé DJ tí a mò sí DJ consequences àti aya rè Olayemisi Williams ti se ayeye ìgbeyàwó won. A kí tokotayà kú oríre .
Read More »Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman. Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Tokunbo Idowu tí ìnagije rè ń jé Tboss, ti se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè ...
Read More »