A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.
A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.* Osù ìségun àséwolè ni yóò jé. A kò níí se gégé ibi, béè ni ìkònà burúkú kò níí kò wá. Nínú Osù yìí, a ó ségun òtá ilé àti tòde, a ó réyìn ...
Read More »
A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.* Osù ìségun àséwolè ni yóò jé. A kò níí se gégé ibi, béè ni ìkònà burúkú kò níí kò wá. Nínú Osù yìí, a ó ségun òtá ilé àti tòde, a ó réyìn ...
Read More »Àwon ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Nina, Alex, Cee-c Tobi àti Miracle ni won ti ya àwòrán pèlú asojú beat FM, Toolz lóòní gégé bí won se bèrè ìrìn àjò won léyìn ìgbélé won.
Read More »Ní ìsàlè ni Àwòrán ayeye ojó ìbí Richmond, omokùnrin gbajúgbajà Òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Ibironke Ojo Anthony, tí a mò sí Ronke Oshodi Oke. Omokùnrin tí ó rewà, tí ó se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè, ...
Read More »Ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé APC ni ó ti kí Ààre Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi. Bauchi tí ó jé òkan Lára àwon gbòógì tí ó máa n gba àlejò Buhari láti ìgbà tí ó ti di Ààre .
Read More »Láìpé yí ni Davido pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram láti pín àwòrán àti ìtàn ti tàtúù tí ó sèsè yà sí apá tí ó pè ní “30BG” kí ó tó di wípé ó fé se ...
Read More »Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Cee-c ti ya àwòrán pèlú Yaw ti Wazobia FM àti Toolz ti Beat FM lénìí nígbà tí won se àbèwò sí won.
Read More »Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà . Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar ...
Read More »Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto . Ìyá yí pọ̀ Ó ju omi òkun lọ Èdùmàrè Ìwọ tó o dá Ráábí aláṣọ Dákun má gbàgbé Ráábí eléwé Èdùmàrè ṣàánú mi Iná tó ń jó tálákà ní Nàìjíríà Ó dájú pé ó ju ...
Read More »Omo ìbàdàn Ìbàdàn mèsi ògò, n’ílé olúyòlé. Ìlú ògúnmólá, olódò kèri l’ójú ogun. Ìlú ìbíkúnlé alágbàlá jáyà-jáyà. Ìlú Àjàyí , ò gbórí Efòn se fílafìla. Ìlú Látóòsà, Ààre-ònà kakanfò. Ìbàdàn Omo ajòro sùn. Omo a je ìgbín yó, fi ìkarahun ...
Read More »