Ó mà se ooo
Àfi kí olórun, elédùmarè gbà wá lówó ikú òjijì ní orílè èdè Nìjíríà. Kí tún ní eléyìí báyìí olúwa gbà wà, e wo òkú òpò nílè bí won se jó ná tán à kí olórun gbà wá wo.
Read More »
Àfi kí olórun, elédùmarè gbà wá lówó ikú òjijì ní orílè èdè Nìjíríà. Kí tún ní eléyìí báyìí olúwa gbà wà, e wo òkú òpò nílè bí won se jó ná tán à kí olórun gbà wá wo.
Read More »Ní déédé agogo márùn-ún ìròlé àná ni ìjàmbá ńlá tí Ó tún jé mánigbàgbé fún orílè èdè Nìjíríà selè, nígbà tí Tánkà ńlá kan gbiná ní ojú pópó ònà tí ó wà láàrin ìlú Èkó si Ìbàdàn. Òpò àwon èèyàn ...
Read More »Nìjíríà ńlé sunkún Àwon èèyàn ibè ò ye é rérìn-ín òfò Èrín òfò tí won rò pé ti ìdùnú ní se Nìjíríà ìlú tí òmínira rè ti di omi ìnirà Atún ti wálé Ojó wo ni àwa náà yóò gba ...
Read More »A dúpẹ́ o Ikú ti di tiwa A dúpẹ́ o Àwọn èèyàn wa ò figi da mààlúù mọ́ AK 47 ni wọ́n ń lò A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run Iṣẹ́ darandaran ti di iṣẹ́ dánràndáràn Èdùmàrè a dúpẹ́ o Ẹ dúró ...
Read More »omokùnrin gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj tí orúko omo náà ń jé Daniel ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná tí a mò sí ojó kerìnlélógún osù kerin odún yii. Kí olúwa kí ó bá ...
Read More »Ohun tí a se lónìí Ìtàn ni b’ódòla Lisabi Agbongbo Àkàlà Fi ìwà akin gba gbogbo Ègbá kalè L’óko erú Olóòyó Ògèdèngbé ń be nínú ìwé ìtàn ìjeshà Asíwájú rere ní se Moremi obìnrinkùnrin n’ífè ńkó, a kò le gbàgbé ...
Read More »Èro àlọ, Ẹ wá gbọ́, èrò àbọ̀, Ẹ wá tẹ́tí sími Oògùn ọlá tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rí ní mo fẹ́ wí f’áyé Oògùn ọrọ̀ tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà ní mo fẹ́ ròyìn Àtọjọ́ mo ti dáyé, Àtọjọ́ mo ti ń ...
Read More »Ìgbà kò lo bí òréré Ayé kò lo bí òpá ìbon, Ìgbà kan ńlo Ìgbà kan ńbo Kí elédùmarè jé kí á n’ígbà tó dára n’ílé ayé wa Ìgbà kan ni ogún náírà yí níyì púpò Sùgbón nísìnín Ó ti ...
Read More »Gégé bí a ti mò wípé eré bóòlù ife àgbáyé ńlo lówó. Ahmed Musa tí Ó jé òkan Lára àwon omo agbábòòlú Nìjíríà ti gbá bóòlù méjì òtòtò wo ilé àwon alátakò won tí a mò sí ikò Iceland.
Read More »