Aja To Rele Ekun To Bo..
Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...
Read More »
Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...
Read More »Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...
Read More »| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa ...
Read More »Ladekoju Oore Yeye Osun o! E ku odun o! Osun Sengese Oyeyenimo a gbe wa o! Aase! Photo Cc – Bekky Amusa
Read More »| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio gbo adura wa o yio si bawa tu ile aye to ...
Read More »“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo I will have enough ...
Read More »Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa. Ibeere talo daran ...
Read More »Hummmmmm onilari koseda tomola #woo_orewa Bo ba ndara fun o loni mase fi omolakeji re se yeye Mofe koranti pe kise agbara re ni ipo towa loni #gbomi_dada Iyanju lagbe ngba obami oke lo nmusu(yam) ta, bi agbara ba nbe ...
Read More »| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin tu ku imura toni, aku isimi opin ose emin wa yio se ...
Read More »