Home / Àṣà Oòduà / Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC

Ijoba apapo ti fowo si aba ti awon ajo NCDC gbe lo si odo Aare.


Ijoba fi aaye sile ki awon ara ilu maa rin maa yan fun ose merin miiran. Ni eyi to maa tun je ki won mo odo ti won maa da orunla si.


Ijoba apapo si salaye pe isede naa wa ni awon ijoba ibile mejidinlogun kaakiri orileede yii. Won ni ijoba ipinle maa kede awon ijoba ibile naa.
Awon moto ti le rin lati ipinle kan si ekeji bayii. Won si gbodo tele gbogbo ofin ajo yii.

Awon ofin bii ki won ma se gbe ju iye ero ti ijoba fowo si lo, won gbodo lo ibomu ti won ba ti wa pelu ero, won gbodo rin ni asiko ti ipinle kookan ba fi aaye sile ti won ni ko si isede ati awon ofin to ku.


Awon akekoojade naa maa wole pelu atele ofin ti ijoba ipinle kookan ba laale fun won. Awon ipinle kookan lo maa salaye awon akekoojade to letoo si iwole ninu awon olodun kefa, olodun kesan-an ati olodun kejila abi gbogbo won lo si maa wole. Gbogbo eyi ni ijoba ipinle maa yanju.
Awon baluu naa ti le fo pelu atele alaale ijoba.


Arun covid-19 naa si n po sii ni orileede ni eyi ti ko je ki awon ajo naa mo ohun ti won maa se.

Won ni opo ti awon ti se ayewo fun pe won ni arun naa ni won n sa lo si ile won.

Ti awon ba si pe won, ija ni won n gbe pade awon. Eyi tun ko awon ajo yii lominu. Won si parowa si awon ara ilu lati fowo sowopo pelu awon ki arun naa le tete di ohun igbagbe.

Yínká Àlàbí

About ayangalu

x

Check Also

mko

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola À ṣẹ kò sééyan táyé ò lé bá ṣọ̀tá, ó tún hàn pé wọ́n le bínú òkú ọ̀run , yàtọ̀ sèèyan tí wọ́n jọ ń wà láyé. À bí kín ní ká tí pé tàwọn kọ̀lọ̀rànsí t’ọ́wọ́Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ti tẹ̀ báyìí pé wọ́n digunjalè sọsẹ́ nílé olóògbé Olóyè Moshood Abíọ́lá tó wà ní Ìkẹjà nílùú Èkó níbi tí wọ́n ti jí nǹkan tó tó ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mílíọ̀nù lọ. Abíọ́lá ló jáwé olúborí ...