Home / Àṣà Oòduà / Odu Ifa Ofun Meji/Orangun Meji Eepa Odu

Odu Ifa Ofun Meji/Orangun Meji Eepa Odu

 | | | |
  |    |
 | | | |
 |   |

 

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si ku imura toni, oro wa yio dayo loni o ase.
Odu ifa OFUN MEJI/ORANGUN MEJI EEPA ODU! Lo gate laaro yi, ifa yi fore omo lopolopo fun akapo ti odu ifa yi ba jade si, ifa ni ki akapo yi rubo wipe oun koni jeki ile re o sofo fomo laelae.
Ifa naa ki bayi wipe:
Ofun nihin
Ofun lohun
A difa fun Ayò eyiti yio ko ile re ti yio kun, won ni ko karale ebo ni ki o wa se (obi meji……ati igba ewe ayajo) o kabomora o rubo won se sise ifa fun Ayo si bi omo mejidinlaadota, ile Ayo wa kun sososo fomo o wa njo o nyo o nyin awo awon awo nyin ifa, ifa nyin eledumare oni nje riru ebo a maa gbeni eru atukesu a maa da ladaju ko pe ko jina ifa wa bami ni jebutu omo nje jebutu Omo ni a nba awo lese obarisa.
Ayo wa fiyere ohun bonu wipe:
E wole ayo e womo o
E wole ayo e womo
Eewo orisa aki nbale ayo laikun
E wole ayo e womo.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe gbogbo aboyun ile yio bi were awon agan yio towo ala bosun, gbogbo eni to ti bi koni yanku o, ile wa koni sofo, omo wa koni pedin nitori omo ayo ki npedin, ile wa yio maa kun fun omo nigbagbogbo ni o aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

 

English Version:

Good morning my people, how was your night? May today bring us abundant joy ase.
It is OFUN MEJI/ORANGUN MEJI (EEPA ODU)! Corpus that revealed this morning, ifa foresee the blessings of plenty child for whoever this corpus revealed out for, ifa advised him/her to offer sacrifice very well.
Hear what the corpus said:
Ofun nihin
Ofun lohun
It cast divined for Ayo the one that will build her house and full it, when she was advised to offer sacrifice so that she may be fruitful and full up her house with child, (two kola nuts…….and ifa leaves) and she complied, aftermath Ayo born forty eight child and her house was full, she started dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising God.
She started singing the song of ifa that:
Come and see the house of Ayo with child o 2*
It is forbidden to see the house of Ayo in empty
Come and see the house of Ayo with child.
My people, I pray this morning that all pregnancy woman will deliver safely and all barrenness woman will have their own child today, our house will never be empty, it will always be full with children and none of them will get lost in our present because a child of Ayo do not get lost ase.

 

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...