Ijamba oko waye ni Victoria Island lonii Posted by: oodua in Àṣà Oòduà 0 Ijamba oko to waye lonii ni agbegbe. Ozumba Mbadiwe, VI, niluu Eko. Oko ajagbe akeru naa run mo awon oko bi merin kan nigba ti bireki re ko muu mo. Enikeni ko fara pa, dukia lasan lo sofo. Àṣà Yorùbá 2015-10-16 oodua tweet