Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?
Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii:
https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?
Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii:
https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Tagged with: Àṣà Yorùbá
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo