Home / Àṣà Oòduà / Omo yibo sepe fun Yoruba lori oro Biafra ti won fe da sile

Omo yibo sepe fun Yoruba lori oro Biafra ti won fe da sile


Awon omo Yibo ti bere si ni soko oro si iran Yoruba to ri wi pe won fe pin kuro ninu orileede Naijiria. Won fe da Biafra sile, won ni awon ko ba Naijiria se mo. E dakun, e wo ni ti Yoruba ninu oro yii? Kilode ti won ko ja ija ti won ja lakoko yii nigba ti omo won wa lori oye? www.Olayemioniroyin.com

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?