Home / Àṣà Oòduà / Oruko kan fun arakunrin yii

Oruko kan fun arakunrin yii

E dakun, e bawa fun arakunrin yii ni oruko kan ?

About ayangalu

5 comments

  1. Okele rapata ! omi obe sororoooo !

  2. Efi le ebi ni o pa bo ya o gba awe biri biri 21 days e mon

  3. shamu shamu oninu bi te ejo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo