Home / Àṣà Oòduà / Eku Apere Ninu Ile Nla

Eku Apere Ninu Ile Nla

Moki gbogbo apapo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi ooo
Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.)
(Ilosiwaju ishese lo jemi lo gun ooo)

EJOWO OO E NPE MI SI AKIYESI

Oruko mi ni
iyin oluwa moje enikan tioma na owo die fun ololufemi latari wipe daddy mi lowo lowo emi nikan sini mummy mi bi fun daddy mi mose alaba pade omokunrin kan ti oruko ee nje bolaji kasimu emi ati omokunrin yi jo nfe ara wa lojo kan tinse ojo aiku tiamo si ojo sunday ni mogbe losi clup tiamo si sho lojo na gbogbo owo tinbee ninu bag mi lojo yen ni se #97,000 owo yi je owo daddy mi tiwon fi ranmi nise wipe timo ba ti kuro ni sho lojo yen kin lo fi sanwo school mi.mosi se alaye bee na fun bolaji kasimu tinse afesona mi lojo na komo wipe daddy mi ti yan awon ore kan timi wipe kioma so mi kakiri nibi ti emi ati afesona mi tinjo lowo ase afesona mi tinfi ogbon ogbon yo owo momi lara laisi mo
opelope awon ore mi to snap wa lojo na oko.mi kotimo wipe asiri titun oo .mosi bere owo na lowo ee oso wipe ohun kori ooo

IBERE EJOWO ETOMI SI ONA OO

Se kin fi photo yi ran kiole mo wipe
Asiri ohun titun kiole ko leko wipe ole ko dara

tabi
Kin gbagbe nipa ee

Abi

Kin kuku fi sile sugbon moni ife ee gan ooo

KIN NI KINSE OO

(.Totofun eee ooo.)
Ojogbon Awo Mimo
Afifadara Kinnihun Orunmila

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo