–Tí ó sì dá àpá sí won l’ára.
Nígbà tí a wà lénu síse àtakò àláfíà sí ilé ìjoba Makurdi lóòní láti jé kí ìjoba gbárùkù láti jé kí won f’owó sí owó ntanràn jíjeko (Anti grazing bill) sínú òfin àti láti fajúro sí orísirísi àbùkù /òròìwòye ti àwon Miyetti Allah Cattle Breader’s Association (MACBAN) ,wón tún pa àwon àgbè oníresì tí kò mo nkankan lára ní ìsodá bírìjì ilé-ìfowópamó, Àríwá (north bank).
Nígbà tí won ń gbin ìresì lówó ni àwon darandaran sí wo inú oko won tí àwon Eran won sì ń je oko won. Èsì ni è ń wò ní ìsàlè yìí bí won se gbé àwon àgbè tí ó se l’ése lo sí ilé-ìwòsàn ifáfitì ìjoba ìpínlè Benue (Benue state university Teaching Hospital).Àwon ènìyàn wònyí (fúlàní) tún fi ara won hàn bí ó tilè jé wípé òfin ti báwa bu owó lù ú ìwé ntanràn jekojeko Anti grazing bill. Àwon fúlàní darandaran tún ń da àwon ònilè àti àwon tí ó ń fé àláfíà àwon ènìyàn ìjoba ìpínlè Benue láànú….
Continue after the page break for the English translation.
Pages: 1 2