Home / Àṣà Oòduà / Oko mi fi mí sílè nítorí pé mi ò tí bímo. Okàn mi ń pòrúrú… Egbàmí!.

Oko mi fi mí sílè nítorí pé mi ò tí bímo. Okàn mi ń pòrúrú… Egbàmí!.

…Mi ò ti è mo bí mo se fé bèrè. Ó dàbí kí ń parí gbogbo rè.

Oko mi sèsè fi mí sílè torí mi ò tíì bímo àti wípé kò fé kí won gba àtò rè àti eyin mi kí won so ó d’omo . A ti ń gbìyànjú fún odún kan àti díè.

Eni tí mo se nkan ribiribi fún òun ló ti fimí sílè yí. Mi ò mo bí mo se fé kojú da àwon ebí mi. Ojú ń tìmí púpò.

Olórun ti kò mí sílè…

Báwo ni mo se fé bèrè ayé tuntun, nítorí kò yémi mó.

Kò le rorùn fún mi nítorí wípé mo ti se ohun ribiribi nínú ìgbéyàwó yí. Mo ti se òpòlopò nkan nítorí ìfé. Ó le gan fún mi àti wípé èmi ló pa lára jù.

Sé mà le là á kojà….

 

Continue after the page break for English translation!

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?