Home / Àṣà Oòduà / Yomi Fabiyi ni Eniola Omoshalewa Eunice fi èsùn ìbálòpò kàn.

Yomi Fabiyi ni Eniola Omoshalewa Eunice fi èsùn ìbálòpò kàn.

   Ogún-l’ógbòn àwon eléré orí ìtàgé ni ó n fi tipátipá béèrè ìbálòpò lówó àwon èèyàn láti le jékí won hàn nínú eré ti orílè èdè Nàíjíríà (Nollywood) gégé bí ìyá kan àti eni tí ìsèlè yí selè sí se fi èsùn kan olùdarí eré Fabiyi.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...