Home / Àṣà Oòduà / Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá.

Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá.

Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá.

Ní òpópónà Uselu ní ìlú Benin ti ìpínlè Edo ni àgbàrá ti gbalè gbalé léyìn òjò ñlá tí ó rò . òpòlopò okò ti omi gbé lo, òpó àwon awakò ni omi gbé lo pèlú súgbón tí awon míràn fi esè fe.
Òpòlopò ònà tí èèyàn le rìn náà ni omi ti gbà tí kò sì se é rìn mó látàrí òjò tí ó fa àgbàrá ní gbogbo ìgbà.
Kódà òpò ilé tí ó wà ní ègbé òná bí ó se tò lo ní ojú ònà ni ó ti wólé.
Gégé bí a se gbó télè wípé omobìnrin kékeré kan ni òjò gbà ní owó ìyá rè ní ojú ònà yí náà, tí won kò sì rí osú rè láti bí òsè mélòó séyìn.
Èbé ni à ñ be àwon ìjoba kí won jòwó bá wa se nkan sí èyí, ñse ni ó dàbí eni wípé ó ti n di gbogbo ìgbà.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo