Home / Àṣà Oòduà / Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo

Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo

Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo
Ìròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí

Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo.


Aso ibomu naa dara de bi wi pe o see fo, ti eniyan si maa tun rii lo.


Oga ile-iwe naa, Alagba Abayomi Salami ati awon alase to ku ni won lo pese ohun iranwo naa fun gomina Seyi Makinde nigba ti komisona fun eto ilera ni ipinle Oyo, Dokita Bashir Bello si teeo gbaa. O si fi emi imoore han fun Fasiti naa.


Fasiti naa tun se ìleri pe ise ti n lo lowo lati pese “Ventilator” fun ijoba ipinle Oyo. Alagba Salami ni eyi maa je ara iranlowo awon lati gbogun ti ajakale arun covid-19.

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.