Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán èyìn Chidinma Ekile tí ó rewà .

Àwòrán èyìn Chidinma Ekile tí ó rewà .

 

Òrò tí ó gbòde kan ni wípé Chidinma Ekile ti darapò mó egbé burúkú àti wípé ó ti n kégbékégbé látàrí wípé ó ya tàtúù dí èyìn rè .
Chidinma Ekile níbi ayeye kan tí ó wo aso tí ó sí èyìn sílè èyí tí ó gbé àwòrán tí ó yà sí èyìn rè jáde, tí ó sì ya òpò lénu sùgbón àríyànjiyàn ti wà wípé làálì lásán làsàn ni sùgbón àwon kan ta ko èyí.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...