Home / Àṣà Oòduà / Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….

Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….

Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won n sare soke sodo ki won ma ba padanu ise won…

Bee gele ni awon onise ibi pelu n sare soke sodo ti won n wa ebi ti won yoo pa lekun ki odun yi to pari…..

Sugbon labe boti wu ki o ri, aburu kere o tobi ko ni ya nile emi ati eyin ni iwonba eyi toku ki odun yi pari lase Edumare.

ase

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...