Home / Àṣà Oòduà / Èmi ni mo ko àkosílè orin tí Davido sèsè ko tí ó n jé “like that” Teni tí ó jé adá ni lára yá , Teniola Apata.

Èmi ni mo ko àkosílè orin tí Davido sèsè ko tí ó n jé “like that” Teni tí ó jé adá ni lára yá , Teniola Apata.

   Olórin kan ní orílè èdè Nàìjíríà adá ni lára yá Teni ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi hàn wípé òun ni òun ko àkosílè Orin tí gbajúgbajà olórin Davido sèsè ko, ó ní òun ni òun ko àkosílè sílè Orin tí a mò sí “like that”.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára