Omo Oodua rere ajirebi?
Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ?
(1) Bojuboju
(2) Bokoboko
(3) Ekun meran
(4) Suwe
(5) Tete
(6) Ere toko ti iyawo
Kò sẹ́ni tí ó ju sáyé, gbogbo wa la ó dìtàn. Aláàfin Àtàndá ti kópa ti wọn, wọ́n ti lọ. Ọdún kẹta rèé tí Aláàfin Ọláyíwọlá ọmọ Adéyẹmí yíjú kúrò níhìn-ín, Ọláyíwọlá kọjú sáwọn aláṣekù, Baba bá wọn lọ. Iṣẹ́ tí wọ́n ṣe é lẹ̀ là ń sọ, tó dìròyìn. Bí a ti ń sọ ọ̀rọ̀ nípa Ọmọ Ìbírònkẹ́ lónìí, àsìkò ń bọ̀ tí àwọn kan náà ó sọ nípa tiwa. Kí layé á sọ nípa tèmi-tìrẹ? Ìlẹ̀pa dòdò kó ...
Kite ati table soccer
Kite ati table soccer