Home / Àṣà Oòduà / Ejowo bawo ni ase le se oro yi ?

Ejowo bawo ni ase le se oro yi ?

Lojo kan mo nlo si ilu keji legbe abule wa emi pelu agbebo adie merin ati agbado abo kan lojiji la de eti odo kan sugbon oloko oju omi ni nko ni anfani lati ko gbogbo awon eru mi lekan soso lodi keji odo kolokolo kan lo duro to nwo feto feto boya ebi npa ni ejowo bawo ni mo se le ko eru yin lemeji pere nitori ki ma ba padanu nkan kan ninu awon eru yi bawo ni kin se gbe eru naa lemeji koja odo pelu alaye ni soki boya nkan ti mo nro leyin naa nro ?

ibeere

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...