Àti ilé ìwé e gírámà ni èmi àti Kọ́lá ti jọ ń fẹ́ ra wa. Àwọn òbí i mi ò kí ń fẹ́ rí Kọ́lá pẹ̀lú u mi nítorí ààfín ni. Nígbà tí mo fẹ́ wo ile ìwé gíga ni ...
Read More »
Àti ilé ìwé e gírámà ni èmi àti Kọ́lá ti jọ ń fẹ́ ra wa. Àwọn òbí i mi ò kí ń fẹ́ rí Kọ́lá pẹ̀lú u mi nítorí ààfín ni. Nígbà tí mo fẹ́ wo ile ìwé gíga ni ...
Read More »Sunday Igboho, ti kéde rẹ̀ fún gbogbo ọmọ Yorùbá pé ìforúkọsílẹ̀ láti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àbò “Iru Ekun Security Network” jẹ́ ọ̀fẹ́ ti kò sì ní ná kọ́bọ̀ kankan fún ẹnikẹ́ni tó fẹ́ yọ̀ǹda ara rẹ̀ fún àbò ilẹ̀ ...
Read More »Kò sẹ́ni tí ó ju sáyé, gbogbo wa la ó dìtàn. Aláàfin Àtàndá ti kópa ti wọn, wọ́n ti lọ. Ọdún kẹta rèé tí Aláàfin Ọláyíwọlá ọmọ Adéyẹmí yíjú kúrò níhìn-ín, Ọláyíwọlá kọjú sáwọn aláṣekù, Baba bá wọn lọ. Iṣẹ́ ...
Read More »Ẹ jẹ́ kí á jọ kí GBajúmọ̀ Akọrin Jùjú nílẹ̀ yìí, Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn ti ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin (83) tó kò lónìí. Kí Olódùmarè ó fi àlàáfíà ṣe ẹ̀bùn Ogbó fún Bàbá
Read More »Gbọ́ ń táwọn èèkàn ìlú ṣọ lẹ́yìn Búrùjí Kashamu Bí ọmọ èèyàn bá wá sílé ayé, ìgbàgbọ́ Yorùbá ní pérúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀ wáyé wá nájà ni. Ènìyàn ò sáà lè tajà tán kò sùn sínú ọjà, àti pé n tí ...
Read More »Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi Ṣé wọ́n ní kìí jẹ́ ti baba t’ọmọ, kó mọ́ ní ààlà. Èyí ló díá fún bí àwọn ẹbí olóògbé Abíọ́lá Ajímọ̀bi tí sàlàyé pé ,kí àwọn olùkẹ́dùn, ó má wulẹ̀ ...
Read More »Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn Ọlọ́jọ́ ń kajọ́, ẹ̀dá ò fiyè si.Ìjọ ọmọ tuntun dáyé, nijọ́ ìdùnnú, ẹ̀rín, òhun ọ̀yàyà fún ẹbí,ará, pẹ̀lú ìyekan. Ṣùgbọ́n kìí rọgbọ ká sàdédé sàfẹ̀kù èèyàn ẹni pékú yọwọ́ ọ rẹ̀ ní dúníyàn. Àsamọ̀ ...
Read More »Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò– Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti ilú Àbújá ti yẹ àga mọ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Adams Oshiomhole nídìí Ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni mẹ́tà ti adájọ́ Eunice Onyemanam sójú fún ni wọ́n fẹnu ...
Read More »O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC Alaga patapata fun eto idibo ni orileede yii, Ojogbon Mahmood Yakubu lo n salaye yii ni ilu Abuja.O ni pelu rogbodiyan to n lo ni ipinle Edo, awon kan ti n ...
Read More »Olorun si maa gbesan iku baba mi – Omo ojo OloyunOjo ketalelogun osu kin-in-ni odun yii ni awon adiha-Moran kan lo yinbon pa Alhaji Fatai Yusuf ti gbogbo eniyan mo si oko oloyun. Lati igba naa ni awon olopaa ti ...
Read More »