Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùn
Aruku madẹgbẹ
Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo
Pages: 1 2
Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùn
Aruku madẹgbẹ
Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...