Home / Àṣà Oòduà / Odaju Abiyamo Fi Ina Jo Omobirin Eni Odun Merindinlogun Loju Ara: O Ni Omo Naa N Se Agbere

Odaju Abiyamo Fi Ina Jo Omobirin Eni Odun Merindinlogun Loju Ara: O Ni Omo Naa N Se Agbere


Omobirin odaran kan ni owo awon olopaa ti te ni agbegbe Ketu niluu Eko pelu bo se fi ero ayoonu iloso jo omo egbon re ti n gbe pelu re, Bimpe Badmus, omo odun merindinlogun, nidi pelu esun wi pe omobirin naa n ba omo lanloodu won lajosepo.

Isele to sele ni opopona Ogunjimi ni obirin naa ti fi ayoonu iloso jo Bimpe loju ara, ikun ati itan omo naa pelu iranlowo awon awon ore meji kan ti won ba a mu omo naa duro.

Gbogbo awon onise ibi naa ni won ti wa ni gbaga awon olopaa bayii nibi ti won ti n jo “azonto” nigba ti Bimpe wa ni osibitu.

Lara oro Bimpe, “Iro ni gbogbo oro naa, ko si nnkankan laaarin emi ati omo lanloodu.”

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo