Home / Àṣà Oòduà / Oko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.

Oko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.

 E jò ó Erànmílówó.
Oko tí ó fémi sílé láti odún mérin séyìn, máa ń fowósí fóòmú rè wípé òun kò tí ní ìyàwó nígbà kúgbà tí ó bá ye kí ó so pé òhun ti láya. Yàtò sí ìyen a kìí sábà ní aáwò kì í sì jowú rárá.
Njé ó n’ìfé mi ní tòótó?
Kílódé tí ó ma ń se báyan?
E jò ó egbà mí ní ìmòràn, kí ni kí n se
Ìnira yí pò púpò, okàn mi sì ń dà rú gidigidi…

English Version
Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...