Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è.
Arewà télè tí ó tún jé òsèré orí ìtàgé sùgbón tí ó ti di Olùwòsàn báyìí, Regina Askia pín àwòrán tí ó rewà ti omo rè tí ó jo ó, omo odún mérìndínlógbòn, orúko omo náà a máa jé Stephanie Hornecker pin sí orí èro ayélujára insitagiramu.
Home / Àṣà Oòduà / Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è
Tagged with: Àṣà Yorùbá