Home / Àṣà Oòduà / Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19
Yínká Àlàbí

Ajakale arun ti gbogbo eniyan ro pe ko ni pe fi orileede yii sile, lo ti ko ti ko lo mo yii. Eyi lo wa bere si ni ko gbogbo aye lominu paapaa orileede Naijiria.


Awon ajo NCDC to n gbogun ti arun coronavirus pokan po lati wo bi won se le fi owo ile too.


Ajo awon onisegun ibile parapo, won sin pa itu meje ti ode n pa ninu igbo pelu egboogi won. Won salaye re replete, ninu eyi ti alaye re ye gbogbo awon ajo yii ni won ti mu meta ninu won.


Iwadii to gbopan si n lo lowo bayii lori awon meta ti won mu fun iwosan arun covid-19

About ayangalu

x

Check Also

seun kuti

Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...