Home / Àṣà Oòduà / Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn

Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn

Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.


Nigba ti esi ayewo jade ni won rii pe o ti ko arun naa. Eyi si mu ki itoju ti o peye bere fun un ni ilu Yaba to wa ni ipinle Eko.

About ayangalu

x

Check Also

ÌKéde ní Yàjóyàjó láti Ilẹ̀ ÌJẹ̀ṣà

Ìkéde ní Yàjóyàjó láti Ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà

Ní ìtẹ̀síwájú orò ìwúyè Ọwá Obòkun Àdìmúlà ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, Ọwá Clement Adésuyì Haastrup, wọ́n ti kéde ìṣéde jákèjádò ìlú Iléṣà. Gẹ́gẹ́ bí Olóyè Àgbà Ọlálékan Fọ́lọ́runṣọ́ tí wọ́n jẹ́ Loro ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ṣe kéde, ìṣéde náà yóò bẹ̀rẹ̀ ní aago mẹ́jọ alẹ́ òní Ọjọ́ Ẹtì, Ọjọ́ kọkànlá títí di aago mẹ́fà Òwúrọ̀ ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin (8pm of April 11 to 6am of April 12, 2025) Kí eku ilé ó gbọ́, kó sọ fún toko o!!! Gbogbo ènìyàn ...