Home / Àṣà Oòduà / Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní Naijiria

Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní Naijiria

Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní Naijiria
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

Eniyan ogun lo tun kun awon ti arun coronavirus n ba ja ni orileede yii ni oni ogbon ojo, osu keta odun 2020.
Metala ni Eko, merin ni Abuja,meji ni kaduna nigba ti okan to ku wa lati ipinle Oyo.
Lagos – 81, FCT – 25, Ogun – 3, Enugu – 2, Oyo – 8, Edo – 2, Bauchi – 2, Osun – 2, Ekiti – 1 ati bee bee lo
Ki Eledua ba wa dawo aburu duro.

About ayangalu

One comment

  1. Won ti di 151. Iroyin yin ti pe leyin

x

Check Also

ÌKéde ní Yàjóyàjó láti Ilẹ̀ ÌJẹ̀ṣà

Ìkéde ní Yàjóyàjó láti Ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà

Ní ìtẹ̀síwájú orò ìwúyè Ọwá Obòkun Àdìmúlà ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, Ọwá Clement Adésuyì Haastrup, wọ́n ti kéde ìṣéde jákèjádò ìlú Iléṣà. Gẹ́gẹ́ bí Olóyè Àgbà Ọlálékan Fọ́lọ́runṣọ́ tí wọ́n jẹ́ Loro ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ṣe kéde, ìṣéde náà yóò bẹ̀rẹ̀ ní aago mẹ́jọ alẹ́ òní Ọjọ́ Ẹtì, Ọjọ́ kọkànlá títí di aago mẹ́fà Òwúrọ̀ ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin (8pm of April 11 to 6am of April 12, 2025) Kí eku ilé ó gbọ́, kó sọ fún toko o!!! Gbogbo ènìyàn ...