Home / Àṣà Oòduà / Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo

Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo

Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

Alaisan marun-un ninu awon ti arun buruku covid-19 ti n ba finra lati bii ose meloo kan seyin gba idande. Yoruba bo “won ni alaare ko ki n ra si inu yara, bi o segun aisan, yoo fi ese ara re rin jade, bi o ba si yiwo naa, won a gbe oku re jade”.

Eyi lo sele si awon marun-un ti arun coronavirus ti n ba poo, ti won si segun arun naa, nitori pe gbogbo ayewo ti won se fun won lera-lera si gbee pe aisan naa ko si lara won mo.

Minisita eto ilera Dokita Osagie Ehanire ati ajo NCDC se tun n parowo si gbogbo omo Naijiria, won ni arun naa ko tii ni oogun kan gbogi nipa idi eyi, ki awon eniyan so ewe agbeje mowo. Ki onikaluku si gbe inu ile re gege bi gbogbo eka ijoba se n forere.

http://iroyinowuro.com.ng/2020/03/30/ori-ko-eniyan-marun-un-yo-lowo-coronavirus-lekoo/

About ayangalu

x

Check Also

ojo keji

Ó San Owó Ilé Ìwé Mi Títí Mo Fi Jáde, Ṣùgbọ́n Mo Fi Májèlé San!

Àti ilé ìwé e gírámà ni èmi àti Kọ́lá ti jọ ń fẹ́ ra wa. Àwọn òbí i mi ò kí ń fẹ́ rí Kọ́lá pẹ̀lú u mi nítorí ààfín ni. Nígbà tí mo fẹ́ wo ile ìwé gíga ni bàbá à mi ní àìsàn an rọ́pá, rọsẹ̀,ọpẹ́lọpẹ́ kọ́lá tó san owó ilé ìwé è mi láti ìgbà tí mo wolé ẹ̀kọ́ gíga títí mo fi jádé. Nígbà ti mo lọ ṣe agùnbánirọ̀ mo pàdé sẹ́nátọ kán,èmi àti ẹ̀ sì ...