Home / Àṣà Oòduà / Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki
Lati owo
Yinka Alabi
Ijoba apapo orileede Naijiria ni o ti ni ki Ogbeni Omoyele Sowore ti o je oludari “iroyin ayelujara Sahara” ati Sambo Dasuki ti o je oluba-Aare damoran pataki (NSA) nigba isejoba Goodluck Jonathan maa wa jejo lati ile ni osan oni ojo kerinlelogun, osu kejila odun 2019.


Minisita eto idajo ni orileede yii, Abubakar Malami ni o gbe ejo naa kanri nigba ti ile ejo giga ti ni ki won maa wa jejo lati ile sugbon ti ijoba apapo ni ko dara ki a fi ina si ori orule sun.


Awuyewuye ti wa n po lori ejo naa ni orileede yii ati ile ibomiran.
Koda ija waye ni ana ode yii lori ki ijoba apapo le fi Sowore sile.


Abubakar Malami ni nigba ti ile ejo ti le ni kii won maa wa jejo lati ile pelu awon nnkan iduro won, to won si ti yege gbogbo nnkan naa, o ni ki won maa lo ile, ki won si ma se gbagbe adehun won.

iroyinowuro

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.