Home / Àṣà Oòduà / Ilé-ìwé Chrisland s̩e ìrànló̩wó̩ fún àwo̩n tó kù díè̩ fún l’Ekoo

Ilé-ìwé Chrisland s̩e ìrànló̩wó̩ fún àwo̩n tó kù díè̩ fún l’Ekoo

Aiba won si nibe ni aiba won da sii. Eyi lo mu ki Alaga ile-iwe ati oludari, Mama Winfrey Awoshika ati Ibironke Adeyemi pese iresi, ewa, gaari ati ororo repete fun awon ti o ku die fun ni awujo.



Idile egberun marun-un (5,000) ni won ni lokan sugbon won bere pelu idile egberun kan (1,000) bayii naa.


Won ti bere si ni pin ounje naa fun awon to letoo si, awon idile naa si n rojo adura fun idagbasoke ile-iwe naa.

Ilé-ìwé Chrisland s̩e ìrànló̩wó̩ fún àwo̩n tó kù díè̩ fún l’Ekoo
Ìròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí

About AbubakarMuhd

One comment

  1. Abusi ni ti okun,abusi ni ti osa,olodumare yio busi apo won ni gbogbo igba.

x

Check Also

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn

Ẹ jẹ́ kí á jọ kí GBajúmọ̀ Akọrin Jùjú nílẹ̀ yìí, Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn ti ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin (83) tó kò lónìí. Kí Olódùmarè ó fi àlàáfíà ṣe ẹ̀bùn Ogbó fún Bàbá