Home / Author Archives: Awo (page 28)

Author Archives: Awo

Àwòrán Adesua Etomi níbi ayeye ìgbéyàwó ìsènbáyé rè.

    Òsèré tí ó gbajúgbajà, Adesua Etomi tún yo ní àrà òtò, sé e mò wípé òtò l’omo oba n rìn . Ó ti è ti rewà jù òun gan ni a ò bá ma pè ní Òkín l’áwùjo ...

Read More »

Beverly Naya, Stephanie, Toyin Abraham, Juliet: ta ni ó ró Aso ebí yí jù.

Tani Aso yí dára jù lára rè láàrin àwon arábìnrin arewà méwàá yí. E rò ó e tó mú o, Beverly Naya rewà púpò, Stephanie rè é ojú kò kúrò lára rè, Toyin Abraham dàbí egbin ní tirè, Juliet kò ...

Read More »

Somkele Iyama wo aso tí kò bo omú ló sí ayeye ìgbéyàwó BankyW àti Adesua Etomi.

Arábìnrin tí ó rewà tí ti jé kí elénu sónu níbi aso tí ó wò tí ó dùn tí ó sì tún se òwón (n se ni ó dàbí eni wípé ó wo bùbá àti ìró)ó wò lo sí ìbí ...

Read More »

Okùnrin yí ni ó te omú obìnrin yí tí ó sì jé kí òpò ma sòrò .

Okùnrin yí ni ó te omú obìnrin yí tí ó sì jé kí òpò ma sòrò . E gbó kí ló n selè níbi àwòrán yí? Mo ti è rò wípé arábìnrin yí kò ní gbà fún arákùnrin yí, okùnrin ...

Read More »

Àwòrán Olusegun Obasanjo tí ó yà ní ìgbà tí ó ti pé tí ó yà ní kété tí won fi sílè ní èwòn.

Àwòrán Olusegun Obasanjo tí ó yà ní ìgbà tí ó ti pé tí ó yà ní kété tí won fi sílè ní èwòn. Olusegun Obasanjo níbi ìsìn ìdúpé léyìn ìgbà tí won da sílè l’éwon ní odún 1998. Owó mà ...

Read More »

Àwon òdó se ayeye ojó ìbí fún Ààre télè, Goodluck Ebele Jonathan ní ìgbà tí ó pé omo ogóta odún (60th).

Ogúnl’ógbòn àwon òdó ni won péjú níbi ayeye ojó ìbí Ààre orílè èdè Nàíjíríà télè, Goodluck Ebele Jonathan láti ba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo ogota odún. E wo àwòrán n’ísàlè .

Read More »

“Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .

     Òkan lára àwon Olólùfé obìnrin tí ó ti nífèé Wizkid ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi èhónu rè hàn wípé òun nífèé Wizkid sùgbón ó so wípé ànfààní nlá ni kí Wizkid fé òun kí ...

Read More »

Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.

    Arábìnrin yí ni ó ti fún àwon èèyàn ní òrò so léyìn tí ó fi èro ìbánisòrò rè tí ó jé aláwò pupa hàn nínú ilé ìtura tí ó wà làímò wípé òrá ìdáàbòbò èyí tí won ti ...

Read More »

Emma Nyra dùn nínú aso ìwè tí ó wò ní Dubai .

    Olórin orílè èdè Nàíjíríà, Emma Nyra ti gbìmò láti fi èbùn tí olórun fun han gbogbo àgbáyé lórí èro ayélujára ( Instagram). Olórin tí ó n lo ìsinmi rè lówó ní Dubai ti pín àwòrán tí ó yà ...

Read More »

Peter okoye se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún mérìndínlógójì pèlú Omotola, Ebí àti òré.

    Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr. P ti lé odún kan ní àná ó sì se ayeye ojó ìbí náà pèlú àwon ebí àti òré ní ilé rè. Gbajúgbajà òsèré, Omotola náà wà níbè.

Read More »