Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi: Video Player Ọ̀jọ̀gbọ́n Olunlọyọ fi àṣà Yorùbá ti ó ti ńparẹ́ hàn ...
Read More »Ifa naa ki bayi wipe: Òkàn sá
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Mo lero wipe gbogbo wa la sun dokan daradara aku isimi opin ose, mosi fi asiko yi ki gbogbo àwon ore mi ti won je omo leyin kristi wípé eku odun eku iyedun emin ...
Read More »E wo Nkan ti Obesere so Nipa Pasuma Ati Awon Osere Oni Fuji miran !
Gó́mìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin fún ìpamọ́ àti ìgbéga èdè Yorùbá
Aàrẹ Ọ̀nà Kakanfo, Ọ̀túnba Gàní Adams ti wọn ṣe ìwúyè fún ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, oṣù kini, ọjọ́ kẹtàlá ọdún Ẹgbàáléméjìdínlógún fi ẹ̀dùn ọkàn hàn nipa bi àṣà àti ìṣe Yoruba ti fẹ́ parẹ́. Nigba ìwúyè, Ọ̀túnba Gàní Adams ṣe àlàyé ...
Read More »Iwulo Ati Anfaani Ti Orí Nse Ninu Igbesi Ayé Omo Eda Eniyan
Ekaaro eyin eniyan mi, aku ise ana o, a sin tun ku imura toni, mose ni iwure laaro yi wipe Eledumare ninu aanu re koni jeki ire oni yi fiwa sile Àse. Idanileko mi toni da lori orí wa, opolopo ...
Read More »Èsù Óólogbè!
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, bi a se njade lo loni Eledumare ninu aanu re yio jeki ire oni yi je tiwa Àse. Laaro yi mofe soro soki nipa èsù òdàrà, o seni laanu lode ...
Read More »Owó✋lá fi n sisé owó
Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n wòlú Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn ...
Read More »Ìtàn ti a o kà loni dá lórí ìdí ti ọmọ Ẹkùn fi di Ológbò
Yorùbá ma npa ìtàn lati fi ṣe à ri kọ́gbọ́n tàbi fún ìkìlọ̀. Ẹ ṣọ́ra lati fi ìbẹ̀rù àti ojo bẹ̀rẹ̀ ọdún nitori a ma a géni kúrú. Lára ẹ̀kọ́ ti a lè ri fi kọ́ ọgbọ́n ni ìtàn ti ...
Read More »Arewa Toni
Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji
Awon agba osere apanilerin meji
Read More »