Oriki to Orunmila Ifá Olókun, A – sorò – dayò, Elérìn-ìpin, Ibìkejì Èdùmàrè. The Diviner of the Sea, the one who makes affairs prosper, Witness to Creation, Second to the Creator. Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni ...
Read More »Odu ifa IWORI MEJI
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Odu ifa IWORI MEJI lo gate laaro yi, ...
Read More »Odu ifa OYEKU MEJI
|| || || || || || || || Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o ase. Odu ifa to gate laaro yi ni OYEKU MEJI, ifa yi gba akapo ti odu ifa yi ba jade si ...
Read More »Odu Ifa Owonrinpota/ Osa
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi ana, a sin ku imura ise oni, Eledumare yio jeki ose yi je ose ayo ati ...
Read More »Odu Ifa Owonrinwese/ Owonrin Ose
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a si ku ola jimoh oni emi wa yio se pupo re laye o, ...
Read More »Tale Feran Ju Ninu K1 Ati Ksa
Ogulutu Oro Toni 18.08.2016
Hummmmmm ohun ta nfe la ndaso bo koseni tio mope irun ori poju irun ibikan lo woo orewa Nje o mope ohun taba gbe pamo ni I niyi? Moraso ogun mofi han eyan ogbon hummmmmm. gbomi dada Bisu eni bata ...
Read More »Odu Ifa Owonrin Elejigbo/ Otua
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku imura toni, mo gbaladura wipe bi a se njade lo laaro yi aori ...
Read More »Odu Owonrin Alakuko/Irete
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku imura toni o, mo gbaladura laaro yi wipe eledumare yio mu gbogbo nkan to ndena ...
Read More »Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!
A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase! K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »