E MAA WI TELE MI : Ire ayo ni temi losu yii. Ire idunnu ni temi losu yii. Ire owo ni temi losu yii. Edumare foro mi se’yanu lose yii. Igbega ati aseyori ni temi. Osu yii yoo san mi ...
Read More »A o ni jin sofin aye pelu ase Olodumare. Ase o…
Ofun saa lefun Ofun saa losun Ofun saa ni moriwo Ope yeyeye A difa fun Alagemo terekange Tii se Omo Orisa igbowuji Nitori ajeku Baba Alagemo Nitori amunku Baba Alagemo Won ni ki Alagemo losi apookun Kio lo si ilameji ...
Read More »Odu Ifa Irosun Ika/Oromosunka
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, a sin ku isimi oni emin wa yio se pupo re laye ninu alaafia ara o ase. Odu ...
Read More »“B’éni l’ówó bí ò n’íwà, owó olówó ni
B’éni l’áya bí ò n’íwà, aya aláya ni B’éni bí’mo bí ò n’íwà, omo olómo ni If one has money but lack character, it’s someone else money If one has wife but lack character, it’s someone else wife If one ...
Read More »Odu Ifa Irosun Afin/ofun
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi opin ose, eledumare yio rojo ibunkun sinu aye wa loni o ase. Odu ...
Read More »Ounje Emi Fun T’ooro Yii – 29.07.2016
HUN !!! Otito wa da bi Akisa Elegbin ni niwaju Oluwa … WOO ORE WA !! Bawo lo se roo pe o mo (mi) to… Nje iwo ri ara re gege bi Ododo loju gbogbo aye ? ...
Read More »Ogbon O Di Igi A Fi Okun(Rope) …
Ojulu, ti opo-eniyan bama wi won a ni ogbon o di igi a fi okun(rope) won a tun ni kosi abuja(short-cut) lorun ope, sugbon ogbon di igi fun eni ti eledua ba gbon, be sini abuja ‘be lorun ope ti ...
Read More »Olojo Ibi Ti Oni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa Omolola Adex ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Maami Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re ...
Read More »Ire ni mo ko
Ire ni mo ji ri Ire tororo d’ori awa o Ire toorun ogberi o mo o Aase IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »Odu ifa IROSUN OPINNI/ IROSUN ORO
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, gegebi oni se je ojo isegun olorun alagbara yio muwa bori Ogun ota ase. Odu ifa IROSUN OPINNI/ ...
Read More »