Olayemi Olatilewa Ile ise ijoba ipinle Ogun ti pe akiyesi awon ara ilu si iroyin eleje kan ti iwe iroyin kan gbe jade wi pe wahala wa laaarin awon oloja ti won gbe ni agbegbe Akute ati gomina ipinle Ogun, ...
Read More »Iwon ese bata kan pere: E kaabo sinu osu tuntun
#Ogulutu #4 Eyin eniyan mi, n maa ki yin kaabo sinu osu tuntun pelu itan Ogbeni Darby omo ilu Amerika to ti n tawo-tase ninu mi fun igba pipe. Itan aroko ko, bee si ni mi o ni fe ki ...
Read More »Awon olopaa ti mu omo yahoo-yahoo niluu Ogbomoso
OlayemiOlatilewa Owo awon olopaa kogberegbe ti ipinle Oyo ti te onijibiti ori ero ayelujara, Babatunde Fatai niluu Ogbomoso. Tunde to je omo asese jade ileewe Ladoke Akintola University of Technology, eleyii to kale siluu Ogbomosho to wa nipinle Oyo ni ...
Read More »Niluu Ilorin: “Awon osise mefa ti ku, awon kan wa nile iwosan”- Akowe egbe osise
Awon osise ajo olomi ti ipinle Kwara tu jade lojo Isegun to koja yii niluu Ilorin nigba ti won fi ehonu won han nipa owo osu won eleyii ti ijoba ipinle naa ko lati san lati inu osu keje seyin. ...
Read More »Won o je ki Saraki o rona gba leyin to fun awon minisita Buhari lona lo
Olayemi Olatilewa Ile ejo kotemilorun to kale siluu Abuja ti da esun aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki nu patapata. Ninu esun ti Saraki gbe lo si ile ejo, ibe ni Saraki ti n ro ile ejo lati pase ...
Read More »“Eyin ni agbara ati isegun mi l’Ojoosegun”: Ipinle Oyo gba leta Ajimobi
Olayemi Olatilewa Gomina ipinle Oyo, Abiola Ajimobi ti gbe sadankata fun awon eniyan ipinle Oyo fun atileyin ti won se fun un lati segun niwaju ile ejo to n risi awuyewuye eto idibo to waye lojo isegun to koja yii. ...
Read More »Won Fadi Omo Odun Meji Ya Niluu Abuja
Olayemi Olatilewa Omokunrin eni odun merindinlogun (16) kan ti lo foju ba ile ejo niluu Abuja leyin asemase pelu omobirin, eni odun meji (2) kan. Iroyin yii lo jade nigba ti olupejo, ogbeni Adama Musa, eni ti n soju ile ...
Read More »Owo te awon omo egbe okunkun niluu Ado-Ekiti
Olayemi Olatilewa Awon akekoo meji ile iwe gbogbonise ti ijoba apapo (Federal Polytechnic) to kale si Ado-Ekiti ati maanu kan ti n tu foonu se ni agbegbe naa ni won ti ko lo si iwaju ile ejo Majisireeti pelu esun ...
Read More »Ireti Odegbami ja sofo lati di aare FIFA agbaye
OlayemiOlatilewa Bi o tile je wi pe ajo ere boolu ile Naijiria ti n fenu so wi pe gbagbaagba ni awon wa leyin agbaboolu to gba boolu metalelogun (23) sawon ni akoko ti n gba boolu fun orileede Naijiria, ...
Read More »“Bilionu lona bilionu owo naira ni Mimiko dabaru ni ipinle Ondo” – Alagba egbe APC
Olayemi Olatilewa Alaga egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo, ogbeni Isaac Kekemeke ti fesun kan Gomina Olusegun Mimiko to je omo egbe oselu PDP nipa wi pe owo bi tirilionu kan naira (N1 trillion) ni gomina ti je mole ...
Read More »