Ki e to tesiwaju lati ka abala keji iroyin yii, maa royin ki e ka abala kinni na. Eleyii yoo fun yin ni oye ibi ti alaye naa ti bere. E le ka iroyin naa ninu linki isale yii: Bi ...
Read More »Blog Page
Foto Yii Lo N Se Afihan Ohun Ti Awon Omo Nigeria N Ro Nipa Ojo Ola Nigeria
Nje awon eniyan omo Nigeria si ni igbagbo wi pe Naijeria sile goke agba? E se ayewo linki isale yii lati ka ero awon omo Nigeria:
Read More »Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72)
Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba rere. Mi o tile mo iru agbekale asanyan oro ti mi o ...
Read More »Hannah Idowu Dideolu Awolowo Ti Lo Ba Oko Re Lorun
Won ti bere igbaradi, inu osu kokanla odun yii ni won pinnu lati se ojo ibi Ogorun (100) Odun Yeye Oodua. Sugbon iku seka, iku doro, iku mu Hannah Idowu Dideolu Awolowo lo leni odun mokandinlogorun (99). Ki Edua oke ...
Read More »Bukola Saraki Wo Gau: Won Pada ‘geti’ Maanu Naa
Leyin awon esun bi metala ati esun iro funfun ti Bukola Saraki pa nipa jijewo dukia to ni. Ile ise ijoba apapo, eka ti awon onidajo ti pase ki ile ise olopaa ile yii, labe akoso ogbeni Solomon Arase lo ...
Read More »Irawo Olorin Ti Won Yin Ni Bajinatu Lodun 2007 Ti Pe Omo Ogoji (40) Odun Lonii
Osu kewaa odun 2007 ni awon afura si kan gege bi agbanipa bere si ni rojo ibon fun Innocent Idibia ni ibudoko Cele to wa loju ona masose Oshodi si Apapa to wa niluu Eko. Sugbon gege bi Ayinla Omowura ...
Read More »E Wa Wo Ohun Ti Won Se Fun Ole Ti Won Mu N’Ikeja
Ole ti won mu ni agbegbe Ikeja ni yii losan-an ana. Awon eniyan se idajo owo won fun-un lai duro de awon olopaa. Nje o dara ki a maa se idajo owo wa fun awon odaran tabi ki a maa ...
Read More »Aare Ilu South Africa Ti Sofin Lati Maa Sami Si Oju Ara Awon To Ba Ni Kokoro HIV
Aare ilu South Africa, Jocob Zuma, ti fi owo si abadofin lati maa sami si egbe kan oju ara awon ti won ba ni kokoro HIV lara. Won ni nipa sise eleyii, yoo mu adinku ba awon eniyan ti won ...
Read More »Yeepa! Ki le yii?
O Dabi Eni Wi Pe Inu Osupa Ni Maanu Yii Ti Wa
Read More »E Wa Wo Ohun Ti Omokekere Yii Da Lara: Eleyii Koja Afenu So
Lara awon iroyin wa to ti jade tele, awon iroyin lori ate Olayemi Oniroyin, mo se lalaye wi pe Edua Oke ko da ile Adulawo gege bi ibugbe awon otosi ati alaini; awon olori wa lo so ilu wa di ...
Read More »