Home / Àṣà Oòduà / Tai Solarin Dilu Nla

Tai Solarin Dilu Nla

Tai Solarin dilu nla
Tai Solarin ile ẹkọ nla to dilu nla.
Ibi ọgbọn gbe pamọ si.
Arọni imọ ti n ja ni laya bi oke.
Gbékanlùkan isẹ ọpọlọ to fakíki.
Kinihun o jẹran ikaṣi.
To ba jọ bi irọ,
Ẹniso n’Ijgun nibi ise akada gbe gbona bi ajere.

Iba fun dokita ti n fi efun gbomola ni kilaasi.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...