Home / Blog Pagepage 53

Blog Page

Omo Ibadan ati Ankara Gucci !

Read More »

A difa fun Òrúnmìlà lojo ti baba nlo sotu ife…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi opin ose o, bi a se njade lo loni ako ni subu lase Eledumare Àse. Laaro yi mofe fi kayefi kan to sele ni bi ojó mesan seyin ladugbo mi nilu ikorodu ...

Read More »

Owe Toni: Lati owo Jude Chukwuka

Read More »

Oríkì ìbejì

Oriki Ibeji: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí ...

Read More »

Owe Toni: Lati Owo Jude Chukwuka

Read More »

Ìfé Mi (My Love)

Ìfé Mi (My Love) Eni bíi okàn mi Adúmáradán orenté Olólùfé mi àtàtà Ìfé re ní n pa mí bí otí òyìnbó Lá ì gbó ohùn re Mi ò lè sùn mi ò lè wo Léyìn re kò sí e ...

Read More »

ORÍLÈ ÈDÈ MI

ORÍLÈ ÈDÈ MI Nàìjíríà ìlú mi pàtàkì Ìlú t’ókún fún ogbón Pèlú òpòlopò àwon òjògbón Ilé ogbón Tí a ti n hun àgbòn ìwà ìbàjé S’ogúndogójì di ààyò àwon òdó Òsèlú di ohun wón k’èyìn sí Egbé òsèlú di ìkan ...

Read More »

Awakò kan tí kò fi ara balè ní ojú pópó ti fi okò fó orí omokùnrin kan ni ìpínlè Edo.

Òdókùnrin kan ni ó se àgbákò ikú òjijì ní ojó mélòó séyìn ní ìlú Jatu ní ìpínlè Edo, nígbà tí ó n gbìyànjú láti fònà sí òdì kejì, arákùnrin yí ni okò tí o n sáré fó ní orí tí ...

Read More »

Reekado banks wà pèlú àwon òdóbìnrin tí won yááyì “ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà lójojúmò.

Ìkan lára àwon omo olórin abé ikò Marvin, Reekado banks pín àwòrán sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram, èyí tí ó yà pèlú àwon òdóbìnrin tí won férè wà ní ìhòhò. Tí ó sì ko síbè pé ...

Read More »

Oríkì Ìjẹ̀bú

Oríkì Ìjẹ̀bú Ìjẹ̀bú ọmọ alárè, Ọmọ awujálè, Ọmọ arójò joyè, Ọmọ alágemo Ògún, Ọmọ aladìye ògògòmógà, Ọmọ adìye bàlókùn, Ara òrokùn, Ara ò radìye, Ọmọ ohun ṣéní, òyòyò mayòmo ohun ṣéní, olèpani, ọmọ dúdú ilé komobe ṣe níJósí, Ọmọ moreye ...

Read More »