. AJE NIMO FẸẸ! Ohun aje f’oju miri ẹnu o le sọ; Oju miri to lori ọrọ aje; Owo(business) f’ẹgbin rẹmi lara; Ninu ẹgbin lọla fiṣe ile; Ọrọ kobakungbe inu iṣẹ-aje ni ngbe. Aje ogugu ni sọ; Onisọ iboji o; ...
Read More »Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun.
Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun. Arákùnrin kan ni ó so àwon táyà okò tí ó ti bàjé yí di tábìlì aláfé, okùnrin yí tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà. Kí ...
Read More »Àwon ìbeta tí ó rewà yí tí ewà won sì wuni yí se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tó yááyì.
John, Peter àti Jamie Obidiegwu, ìbeta se ayeye ojó ìbí won ní àrà òtò. Ayeye ojó ìbí míràn ni ó jé fún àwon ìbeta tí ó jé okùnrin yí, ohun ayò ni ayeye yí sì jé fún won tí won ...
Read More »Ìgbeyàwó alárédè ti DJ consequences àti Olayemisi Williams.
Arákùnrin tí ó ń se isé DJ tí a mò sí DJ consequences àti aya rè Olayemisi Williams ti se ayeye ìgbeyàwó won. A kí tokotayà kú oríre .
Read More »Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman
Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman. Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Tokunbo Idowu tí ìnagije rè ń jé Tboss, ti se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè ...
Read More »Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.
Èèyàn méjì òtòtò ni ó di olóògbé látàrí àgbàrá òjò tí Ó gbé won lo, tí Óní sì pa wón sí gbàgede enu àbáwolé ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè Nìjíríà, Nsukka (UNN). Gégé bí ìròyìn se so àwon olóògbé ...
Read More »Wizkid àti ìyá rè ya àwòrán papò.
Gbajúgbajà olórin afé tí a mò sí starboy, tí Óní tún jé Wizkid ya àwòrán pèlú ìyá rè. Èyí wùwá ooo.
Read More »Odun odun kan ko dun dun
Ko dun bi odun yi ri Odun ti o dun ni odun ominira1960 Odun n dun ni dundun n dun Orile-ede ti n San fun wara ati oyin Orile-ede abinibi Nigeria Adugbo ti n toro omo ale ni ke ti ...
Read More »ỌJỌ́ NÁÀ RÈÉ BÍ ÀNÁ
Ọjọ́ náà rèé bí àná. Bí eré bí àwàdà; Kánmọ́kánmọ́ l’ọjọ́ ń șí lọ bí ẹyẹ. Ọjọ́ náà rèé bí àná; Tá a bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ ìrìn-àjò ọ̀hún. Òjòó rọ̀ wọ̀wọ̀. Afẹ́fẹ́ fẹ́ ilẹ́lẹ́-ilẹ́lẹ́. Ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀ẹ́ m’igi oko dìgbàdìgbà. Ojúu sánmọ̀ọ́ ...
Read More »Àwon Akékòó Ogbà Fémi jà fún ètó won
Bí a bá pè é ní ìjà láàrin akékòó eka èkó gèésì (Department of English ) àti ti àwon eka èkó nípa òfin (faculty of law) ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university wo ìyá ìjàkadì Látàrí wípé àwon ...
Read More »