Home / Àṣà Oòduà / Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman

Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman

Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman.

Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Tokunbo Idowu tí ìnagije rè ń jé Tboss, ti se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman.

Ó pín àwòrán òun àti ìyá náà ní àná láti se ayeye fun.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*