Home / Àṣà Oòduà / Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.

Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.

Èèyàn méjì òtòtò ni ó di olóògbé látàrí àgbàrá òjò tí Ó gbé won lo, tí Óní sì pa wón sí gbàgede enu àbáwolé ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè Nìjíríà, Nsukka (UNN). Gégé bí ìròyìn se so àwon olóògbé yí fé fo ònà sí òdì kejì kí ó tó di wípé àgbàrá gbé won ló.
Kí olúwa té won sí aféfé rere.

Àwòrán nkan níyì nínú àwon méjèèjì.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?