Home / Àṣà Oòduà (page 94)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Oríkì Ẹ̀rìn Òsun

Ẹ̀rìn moje ọmọ saaja, Ọmọ eléwé ladogba òróró maro, Ẹ̀rìn wagunwagun Ewá w’Ẹ̀rìn logun eniti yíò wá Ẹ̀rìn logun kowa àpò ide kolowa ọfà, Bàbá kòníbon ajíperin nílé, karo ń lè mọ wọn lójú ogun ẹni Ẹ̀rìn mọ jẹ́ ta ...

Read More »

Ìfẹ́ láàárín ara wa

Ìfẹ́ láàrin ara wa Ìfẹ́ dára, Ìfẹ́ dùn bí a bá pàdé oní tí wá, Ìfẹ́ jẹ́ òhun tí ó má ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn, Yálà ọkùnrin sí obìnrin, Obìnrin sí ọkùnrin, Ìyá sí ọmọ, Bàbá sí ọmọ, Ọkọ ...

Read More »

Ìtẹ́lọ́rùn – #Ìtẹ́lọ́rùnṣepàtàkì.

Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni ìtẹ́lọ́rùn le mú ni jalè, Bí ohun tí a ni kò ...

Read More »

Aṣọ wíwọ̀

Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ...

Read More »

Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn

Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé, Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé, Ìràwò òwúrò tèmi nìkan, Olólùfẹ́ mi, Nínú aba ayé yìí Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ, Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon, Ife ìwọ ...

Read More »

‪#‎Òmìnira‬

  Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú wàhálà ...

Read More »

Ogboni – Isese Lagba

EEPA MOLE !!!

Read More »

ARUGBA is no longer a Virgin maid

Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the people ...

Read More »

Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni Oba méjì, Ifá to Oba o, Òrúnmìlà ni Baba wa, Ifá to Oba o.

Oriki  to Orunmila Ifá Olókun, A – sorò – dayò, Elérìn-ìpin, Ibìkejì Èdùmàrè. The Diviner of the Sea, the one who makes affairs prosper, Witness to Creation, Second to the Creator. Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni ...

Read More »

Odu ifa IWORI MEJI

| | | |  |    |  |    | | | | |  Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Odu ifa IWORI MEJI lo gate laaro yi, ...

Read More »