My motherWho walks in the nightGraceful be thy stepsAs you place your heelOn the head Of a hidden Cobra And it cannot bite you.
Read More »Ogbè Até
Owó òtún mi ni mo fi n gba ire Adífáfún Sará Sará N’ílé olódùmarè la gbé n báwon Lóri orí eni òré òhun tìmùtìmù rere Àtélewó mi òsì Ni mo fi n gba ìfà Adífáfún Sèbí Sèbí N’ílé olódùmare ni ...
Read More »Ará Ọ̀run
Cc – Moyo Okediji
Read More »Foto: Aafin Ogbomoso
Aafin Ogbomoso
Read More »Ifa physiology: Ojú/Eyes
Ojú. Ojú lalákàn fi í sọ́rí. Ojú oró ní í lékè omi. Ojú ò ní tì wá lótù Ifẹ yìí láíláí. Ojú ò níí relé de ìkankan nínú àwa ọmọ Awo. Eyes–Oju With the eyes, the crab watches the ori. ...
Read More »IFA ANATOMY: Etí/ Ear
Etí. Ear, also fringe, edge, border, perimeter. Ó pawo lékèé Ó pÈṣù lólè Ó wá kọtí ọ̀gbọin sẹ́bọ Etí odò yato sétí aṣọ. Ọ̀rọ̀ tí a bá fẹ́ kí aditi gbọ́ Etí ọmọ rẹ̀ là á ti í sọ o. ...
Read More »IFA ANATOMY: Itan / thigh
IFA ANATOMY Itan = thigh. A kì í bá ni tan ká fa ni ní itan ya. Because people are tied by kinship offers them no excuse to rip off the thighs of one another. `Moyo Okediji
Read More »